Ọpọ eeyan lo gboṣuba fawọn ọmogun olufọkansin to koju awọn ọmogun ọlọtẹ ti wọn gbiyanju lati ditẹ gbajọba Aarẹ Patrice Talon orilẹede Benin lọjọ Aiku to kọja. Aarẹ ni igbesẹ awọn ọmogun ọlọtẹ naa le ...